Dáníẹ́lì 6:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó dáa lójú Dáríúsì kó fi ọgọ́fà (120) baálẹ̀ jẹ lórí gbogbo ìjọba náà.+ Dáníẹ́lì 9:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ní ọdún kìíní Dáríúsì+ ọmọ Ahasuérúsì, àtọmọdọ́mọ àwọn ará Mídíà, ẹni tí wọ́n fi jọba lórí ìjọba àwọn ará Kálídíà,+
9 Ní ọdún kìíní Dáríúsì+ ọmọ Ahasuérúsì, àtọmọdọ́mọ àwọn ará Mídíà, ẹni tí wọ́n fi jọba lórí ìjọba àwọn ará Kálídíà,+