-
Dáníẹ́lì 6:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Gbogbo àwọn òṣìṣẹ́ ọba, àwọn aṣíwájú, àwọn baálẹ̀, àwọn olóyè jàǹkàn-jàǹkàn àti àwọn gómìnà ti gbìmọ̀ pọ̀ láti fi àṣẹ kan lélẹ̀ látọ̀dọ̀ ọba, kí wọ́n sì kà á léèwọ̀* pé, láàárín ọgbọ̀n (30) ọjọ́, ẹnikẹ́ni tó bá béèrè nǹkan lọ́wọ́ ọlọ́run tàbí èèyàn èyíkéyìí yàtọ̀ sí ìwọ ọba, ká ju onítọ̀hún sínú ihò kìnnìún.+
-