Jeremáyà 33:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 ‘Ké pè mí, màá sì dá ọ lóhùn, mo ṣe tán láti sọ nípa àwọn ohun ńlá tí kò ṣeé lóye fún ọ, àwọn ohun tí ìwọ kò tíì mọ̀.’”+ 1 Kọ́ríńtì 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nítorí àwa ni Ọlọ́run ti ṣí wọn payá fún+ nípasẹ̀ ẹ̀mí rẹ̀,+ nítorí ẹ̀mí ń wá inú ohun gbogbo, títí kan àwọn ohun ìjìnlẹ̀ Ọlọ́run.+
3 ‘Ké pè mí, màá sì dá ọ lóhùn, mo ṣe tán láti sọ nípa àwọn ohun ńlá tí kò ṣeé lóye fún ọ, àwọn ohun tí ìwọ kò tíì mọ̀.’”+
10 Nítorí àwa ni Ọlọ́run ti ṣí wọn payá fún+ nípasẹ̀ ẹ̀mí rẹ̀,+ nítorí ẹ̀mí ń wá inú ohun gbogbo, títí kan àwọn ohun ìjìnlẹ̀ Ọlọ́run.+