Sáàmù 102:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ó dájú pé wàá dìde, wàá sì ṣàánú Síónì,+Torí àkókò ti tó láti ṣe ojú rere sí i;+Àkókò tí a dá ti pé.+ Àìsáyà 54:7, 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “Torí mo pa ọ́ tì fún ìgbà díẹ̀,Àmọ́ màá ṣàánú rẹ gidigidi, màá sì kó ọ jọ pa dà.+ 8 Mo fi ojú mi pa mọ́ fún ọ fún àkókò díẹ̀ torí inú bí mi gidigidi,+Àmọ́ màá ṣàánú rẹ nítorí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀, tó wà títí láé,”+ ni Jèhófà, Olùtúnrà rẹ+ wí. Jeremáyà 14:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìwà wa jẹ́rìí sí i pé a ti ṣe àṣìṣe,Jèhófà, ràn wá lọ́wọ́ nítorí orúkọ rẹ.+ Nítorí ìwà àìṣòótọ́ wa pọ̀,+Ìwọ sì ni a dẹ́ṣẹ̀ sí.
13 Ó dájú pé wàá dìde, wàá sì ṣàánú Síónì,+Torí àkókò ti tó láti ṣe ojú rere sí i;+Àkókò tí a dá ti pé.+
7 “Torí mo pa ọ́ tì fún ìgbà díẹ̀,Àmọ́ màá ṣàánú rẹ gidigidi, màá sì kó ọ jọ pa dà.+ 8 Mo fi ojú mi pa mọ́ fún ọ fún àkókò díẹ̀ torí inú bí mi gidigidi,+Àmọ́ màá ṣàánú rẹ nítorí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀, tó wà títí láé,”+ ni Jèhófà, Olùtúnrà rẹ+ wí.
7 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìwà wa jẹ́rìí sí i pé a ti ṣe àṣìṣe,Jèhófà, ràn wá lọ́wọ́ nítorí orúkọ rẹ.+ Nítorí ìwà àìṣòótọ́ wa pọ̀,+Ìwọ sì ni a dẹ́ṣẹ̀ sí.