-
Dáníẹ́lì 8:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Àmọ́ bó ṣe ń bá mi sọ̀rọ̀, mo sùn lọ fọnfọn níbi tí mo dojú bolẹ̀ sí. Ó wá fọwọ́ kàn mí, ó sì mú kí n dìde dúró níbi tí mo dúró sí.+
-