Dáníẹ́lì 12:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọ̀pọ̀ máa wẹ ara wọn mọ́, wọ́n máa sọ ara wọn di funfun, a sì máa yọ́ wọn mọ́.+ Àwọn ẹni burúkú máa hùwà burúkú, kò sì ní yé ìkankan nínú àwọn ẹni burúkú; ṣùgbọ́n àwọn tó ní ìjìnlẹ̀ òye máa lóye.+
10 Ọ̀pọ̀ máa wẹ ara wọn mọ́, wọ́n máa sọ ara wọn di funfun, a sì máa yọ́ wọn mọ́.+ Àwọn ẹni burúkú máa hùwà burúkú, kò sì ní yé ìkankan nínú àwọn ẹni burúkú; ṣùgbọ́n àwọn tó ní ìjìnlẹ̀ òye máa lóye.+