Dáníẹ́lì 2:48 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 Ọba wá gbé Dáníẹ́lì ga, ó fún un ní ọ̀pọ̀ ẹ̀bùn tó dáa, ó sì fi ṣe alákòóso lórí gbogbo ìpínlẹ̀* Bábílónì+ àti olórí àwọn aṣíwájú gbogbo amòye Bábílónì. Dáníẹ́lì 5:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wọ́n wá mú Dáníẹ́lì wá síwájú ọba. Ọba bi Dáníẹ́lì pé: “Ṣé ìwọ ni Dáníẹ́lì, tí wọ́n mú nígbèkùn ní Júdà,+ tí bàbá mi ọba mú wá láti Júdà?+ Dáníẹ́lì 5:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Bẹliṣásárì wá pàṣẹ, wọ́n sì fi aṣọ aláwọ̀ pọ́pù wọ Dáníẹ́lì, wọ́n fi ìlẹ̀kẹ̀ wúrà sí i lọ́rùn; wọ́n sì kéde pé ó máa di igbá kẹta nínú ìjọba.+
48 Ọba wá gbé Dáníẹ́lì ga, ó fún un ní ọ̀pọ̀ ẹ̀bùn tó dáa, ó sì fi ṣe alákòóso lórí gbogbo ìpínlẹ̀* Bábílónì+ àti olórí àwọn aṣíwájú gbogbo amòye Bábílónì.
13 Wọ́n wá mú Dáníẹ́lì wá síwájú ọba. Ọba bi Dáníẹ́lì pé: “Ṣé ìwọ ni Dáníẹ́lì, tí wọ́n mú nígbèkùn ní Júdà,+ tí bàbá mi ọba mú wá láti Júdà?+
29 Bẹliṣásárì wá pàṣẹ, wọ́n sì fi aṣọ aláwọ̀ pọ́pù wọ Dáníẹ́lì, wọ́n fi ìlẹ̀kẹ̀ wúrà sí i lọ́rùn; wọ́n sì kéde pé ó máa di igbá kẹta nínú ìjọba.+