Émọ́sì 8:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àwọn tó ń fi ẹ̀ṣẹ̀ Samáríà+ búra, tí wọ́n sì ń sọ pé,“Bí ọlọ́run rẹ ti wà láàyè, ìwọ Dánì!”+ Àti “Bí ọ̀nà Bíá-ṣébà+ ti ń bẹ!” Wọ́n á ṣubú, wọn ò sì ní dìde mọ́.’”+ Míkà 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ọ̀tẹ̀ Jékọ́bù ló fa gbogbo èyí,Ẹ̀ṣẹ̀ ilé Ísírẹ́lì.+ Ta ló fa ọ̀tẹ̀ Jékọ́bù? Ṣebí àwọn ará Samáríà ni?+ Ta ló sì kọ́ àwọn ibi gíga tó wà ní Júdà?+ Ṣebí àwọn ará Jerúsálẹ́mù ni?
14 Àwọn tó ń fi ẹ̀ṣẹ̀ Samáríà+ búra, tí wọ́n sì ń sọ pé,“Bí ọlọ́run rẹ ti wà láàyè, ìwọ Dánì!”+ Àti “Bí ọ̀nà Bíá-ṣébà+ ti ń bẹ!” Wọ́n á ṣubú, wọn ò sì ní dìde mọ́.’”+
5 Ọ̀tẹ̀ Jékọ́bù ló fa gbogbo èyí,Ẹ̀ṣẹ̀ ilé Ísírẹ́lì.+ Ta ló fa ọ̀tẹ̀ Jékọ́bù? Ṣebí àwọn ará Samáríà ni?+ Ta ló sì kọ́ àwọn ibi gíga tó wà ní Júdà?+ Ṣebí àwọn ará Jerúsálẹ́mù ni?