-
2 Kíróníkà 30:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Lẹ́yìn náà, àwọn asáréjíṣẹ́* lọ káàkiri gbogbo Ísírẹ́lì àti Júdà pẹ̀lú àwọn lẹ́tà látọ̀dọ̀ ọba àti àwọn ìjòyè rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ọba ti pa á láṣẹ, ó ní: “Ẹ̀yin ọmọ Ísírẹ́lì, ẹ pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run Ábúráhámù, Ísákì àti Ísírẹ́lì, kí ó lè pa dà sọ́dọ̀ àwọn tó ṣẹ́ kù tí wọ́n sá kúrò lọ́wọ́ àwọn ọba Ásíríà.+
-