25 Ó rí bí ó ṣe sọ nínú ìwé Hósíà pé: “Màá pe àwọn tí kì í ṣe èèyàn mi+ ní ‘àwọn èèyàn mi,’ màá sì pe ẹni tí kì í ṣe olùfẹ́ ní ‘àyànfẹ́’;+ 26 bákan náà, níbi tí a ti sọ fún wọn pé, ‘Ẹ kì í ṣe èèyàn mi,’ ibẹ̀ la ó ti pè wọ́n ní ‘àwọn ọmọ Ọlọ́run alààyè.’”+