Jeremáyà 4:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Nítorí àwọn èèyàn mi gọ̀;+Wọn ò kà mí sí. Ọmọ tí kò gbọ́n ni wọ́n, wọn ò sì lóye. Ọ̀jáfáfá* ni wọ́n nínú ìwà ibi,Àmọ́, wọn ò mọ bí a ti ń ṣe rere.”
22 “Nítorí àwọn èèyàn mi gọ̀;+Wọn ò kà mí sí. Ọmọ tí kò gbọ́n ni wọ́n, wọn ò sì lóye. Ọ̀jáfáfá* ni wọ́n nínú ìwà ibi,Àmọ́, wọn ò mọ bí a ti ń ṣe rere.”