Jóẹ́lì 1:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ẹ kéde* ààwẹ̀; ẹ pe àpéjọ ọlọ́wọ̀.+ Ẹ kó àwọn àgbààgbà àti gbogbo àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà jọ,Sí ilé Jèhófà Ọlọ́run yín,+ kí ẹ sì ké pe Jèhófà pé kó ràn yín lọ́wọ́.
14 Ẹ kéde* ààwẹ̀; ẹ pe àpéjọ ọlọ́wọ̀.+ Ẹ kó àwọn àgbààgbà àti gbogbo àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà jọ,Sí ilé Jèhófà Ọlọ́run yín,+ kí ẹ sì ké pe Jèhófà pé kó ràn yín lọ́wọ́.