Diutarónómì 32:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Torí Jèhófà máa dá ẹjọ́ àwọn èèyàn+ rẹ̀,Ó sì máa káàánú* àwọn ìránṣẹ́+ rẹ̀,Tó bá rí i pé okun wọn ti ń tán,Tó sì rí i pé àwọn tí kò ní olùrànlọ́wọ́ àtàwọn tó ti rẹ̀ ló ṣẹ́ kù. Àìsáyà 60:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn àjèjì máa mọ àwọn ògiri rẹ,Àwọn ọba wọn sì máa ṣe ìránṣẹ́ fún ọ,+Torí ìbínú ni mo fi kọ lù ọ́,Àmọ́ màá fi ojúure* mi ṣàánú rẹ.+ Ìdárò 3:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nítorí ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀ ni ò jẹ́ ká ṣègbé,+Nítorí àánú rẹ̀ kò ní dópin láé.+ Hósíà 11:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ṣé ó yẹ kí n yọwọ́ lọ́rọ̀ rẹ, ìwọ Éfúrémù?+ Ṣé ó yẹ kí n fà ọ́ lé ọ̀tá lọ́wọ́, ìwọ Ísírẹ́lì? Ṣé ó yẹ kí n ṣe ọ́ bí Ádímà? Ṣé ó yẹ kí n ṣe ọ́ bíi Sébóíímù?+ Mo ti yí ọkàn mi pa dà;Lẹ́sẹ̀ kan náà, inú mi ti yọ́* sí wọn.+
36 Torí Jèhófà máa dá ẹjọ́ àwọn èèyàn+ rẹ̀,Ó sì máa káàánú* àwọn ìránṣẹ́+ rẹ̀,Tó bá rí i pé okun wọn ti ń tán,Tó sì rí i pé àwọn tí kò ní olùrànlọ́wọ́ àtàwọn tó ti rẹ̀ ló ṣẹ́ kù.
10 Àwọn àjèjì máa mọ àwọn ògiri rẹ,Àwọn ọba wọn sì máa ṣe ìránṣẹ́ fún ọ,+Torí ìbínú ni mo fi kọ lù ọ́,Àmọ́ màá fi ojúure* mi ṣàánú rẹ.+
8 Ṣé ó yẹ kí n yọwọ́ lọ́rọ̀ rẹ, ìwọ Éfúrémù?+ Ṣé ó yẹ kí n fà ọ́ lé ọ̀tá lọ́wọ́, ìwọ Ísírẹ́lì? Ṣé ó yẹ kí n ṣe ọ́ bí Ádímà? Ṣé ó yẹ kí n ṣe ọ́ bíi Sébóíímù?+ Mo ti yí ọkàn mi pa dà;Lẹ́sẹ̀ kan náà, inú mi ti yọ́* sí wọn.+