Ìsíkíẹ́lì 33:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Èmi yóò mú kí ilẹ̀ náà di ahoro pátápátá,+ òpin á sì dé bá ìgbéraga rẹ̀, àwọn òkè Ísírẹ́lì yóò di ahoro,+ ẹnikẹ́ni ò sì ní gba ibẹ̀ kọjá. Hósíà 5:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ìwà Ísírẹ́lì ti jẹ́rìí sí i* pé ó gbéra ga;+Àṣìṣe Ísírẹ́lì àti Éfúrémù ti mú kí wọ́n kọsẹ̀,Júdà sì ti kọsẹ̀ pẹ̀lú wọn.+
28 Èmi yóò mú kí ilẹ̀ náà di ahoro pátápátá,+ òpin á sì dé bá ìgbéraga rẹ̀, àwọn òkè Ísírẹ́lì yóò di ahoro,+ ẹnikẹ́ni ò sì ní gba ibẹ̀ kọjá.
5 Ìwà Ísírẹ́lì ti jẹ́rìí sí i* pé ó gbéra ga;+Àṣìṣe Ísírẹ́lì àti Éfúrémù ti mú kí wọ́n kọsẹ̀,Júdà sì ti kọsẹ̀ pẹ̀lú wọn.+