2 Àwọn Ọba 17:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ní ọdún kẹsàn-án Hóṣéà, ọba Ásíríà gba Samáríà.+ Ó wá kó àwọn èèyàn Ísírẹ́lì ní ìgbèkùn+ lọ sí Ásíríà, ó sì mú kí wọ́n máa gbé ní Hálà àti ní Hábórì níbi odò Gósánì+ àti ní àwọn ìlú àwọn ará Mídíà.+ Hósíà 9:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Gílígálì + ni gbogbo ìwà ibi wọn ti ṣẹlẹ̀, ibẹ̀ ni mo ti kórìíra wọn. Màá lé wọn kúrò ní ilé mi nítorí iṣẹ́ ibi wọn.+ Mi ò ní nífẹ̀ẹ́ wọn mọ́;+Gbogbo olórí wọn ya alágídí.
6 Ní ọdún kẹsàn-án Hóṣéà, ọba Ásíríà gba Samáríà.+ Ó wá kó àwọn èèyàn Ísírẹ́lì ní ìgbèkùn+ lọ sí Ásíríà, ó sì mú kí wọ́n máa gbé ní Hálà àti ní Hábórì níbi odò Gósánì+ àti ní àwọn ìlú àwọn ará Mídíà.+
15 “Gílígálì + ni gbogbo ìwà ibi wọn ti ṣẹlẹ̀, ibẹ̀ ni mo ti kórìíra wọn. Màá lé wọn kúrò ní ilé mi nítorí iṣẹ́ ibi wọn.+ Mi ò ní nífẹ̀ẹ́ wọn mọ́;+Gbogbo olórí wọn ya alágídí.