Ìsíkíẹ́lì 35:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Bí inú yín ṣe dùn nígbà tí ogún ilé Ísírẹ́lì di ahoro, bẹ́ẹ̀ ni màá ṣe sí yín.+ Ìwọ yóò di ahoro, ìwọ agbègbè olókè Séírì, àní gbogbo Édómù;+ wọ́n á sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.’”
15 Bí inú yín ṣe dùn nígbà tí ogún ilé Ísírẹ́lì di ahoro, bẹ́ẹ̀ ni màá ṣe sí yín.+ Ìwọ yóò di ahoro, ìwọ agbègbè olókè Séírì, àní gbogbo Édómù;+ wọ́n á sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.’”