-
Jẹ́nẹ́sísì 27:41, 42Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
41 Ṣùgbọ́n Ísọ̀ di Jékọ́bù sínú torí pé bàbá rẹ̀ ti súre fún un,+ Ísọ̀ sì ń sọ lọ́kàn ara rẹ̀ pé: “Ọjọ́ tí a máa ṣọ̀fọ̀ bàbá mi ti ń sún mọ́lé.+ Lẹ́yìn náà, ṣe ni màá pa Jékọ́bù àbúrò mi.” 42 Nígbà tí wọ́n sọ fún Rèbékà ohun tí Ísọ̀ ọmọ rẹ̀ àgbà sọ, ojú ẹsẹ̀ ló ránṣẹ́ pe Jékọ́bù ọmọ rẹ̀ tó jẹ́ àbúrò, ó sì sọ fún un pé: “Wò ó! Ísọ̀ ẹ̀gbọ́n rẹ ń wá bó ṣe máa pa ọ́ kó lè gbẹ̀san.*
-
-
Sáàmù 83:4-6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun