-
Sáàmù 130:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
130 Láti inú ibú ni mo ti ké pè ọ́, Jèhófà.+
2 Jèhófà, gbọ́ ohùn mi.
Kí etí rẹ ṣí sí ẹ̀bẹ̀ mi fún ìrànlọ́wọ́.