-
2 Kíróníkà 32:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Nígbà tí Hẹsikáyà rí i pé Senakérúbù ti dé, tó sì fẹ́ gbéjà ko Jerúsálẹ́mù,
-
-
Míkà 1:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Torí, ohun rere ni àwọn* tó ń gbé ní Márótì ń retí,
Àmọ́ Jèhófà ti mú ohun tó burú wá sí ẹnubodè Jerúsálẹ́mù.
-