-
Jeremáyà 22:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 ‘Àmọ́ ojú rẹ àti ọkàn rẹ ò kúrò lórí bí o ṣe máa jẹ èrè tí kò tọ́,
Lórí bí o ṣe máa ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀
Àti lórí bí o ṣe máa lu jìbìtì àti bí o ṣe máa lọ́ni lọ́wọ́ gbà.’
-
-
Ìsíkíẹ́lì 22:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Àwọn èèyàn ilẹ̀ náà ti lu jìbìtì, wọ́n sì ti jalè,+ wọ́n ti ni aláìní àti tálákà lára, wọ́n ti lu àjèjì ní jìbìtì, wọ́n sì ti fi ẹ̀tọ́ rẹ̀ dù ú.’
-