Àìsáyà 1:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Alágídí ni àwọn ìjòyè rẹ, àwọn àtàwọn olè jọ ń ṣiṣẹ́.+ Gbogbo wọn ló fẹ́ràn àbẹ̀tẹ́lẹ̀, wọ́n sì ń wá ẹ̀bùn kiri.+ Wọn kì í dá ẹjọ́ àwọn ọmọ aláìníbaba* bó ṣe tọ́,Ẹjọ́ opó kì í sì í dé iwájú wọn.+ Àìsáyà 5:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àwọn tó ń sọ pé ohun tó dára burú àti pé ohun tó burú dára gbé,+Àwọn tó ń fi òkùnkùn dípò ìmọ́lẹ̀, tí wọ́n sì ń fi ìmọ́lẹ̀ dípò òkùnkùn,Àwọn tó ń fi ìkorò dípò adùn àti adùn dípò ìkorò! Àìsáyà 5:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Àwọn tó dá ẹni burúkú láre torí àbẹ̀tẹ́lẹ̀,+Tí wọn ò sì jẹ́ kí olódodo rí ìdájọ́ òdodo gbà!+ Ìsíkíẹ́lì 22:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Inú rẹ ni wọ́n ti gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ kí wọ́n lè ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀.+ Ò ń yáni lówó èlé,+ ò ń jẹ èrè* lórí owó tí o yáni, o sì ń fipá gba owó lọ́wọ́ ọmọnìkejì rẹ.+ Àní, o ti gbàgbé mi pátápátá,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.
23 Alágídí ni àwọn ìjòyè rẹ, àwọn àtàwọn olè jọ ń ṣiṣẹ́.+ Gbogbo wọn ló fẹ́ràn àbẹ̀tẹ́lẹ̀, wọ́n sì ń wá ẹ̀bùn kiri.+ Wọn kì í dá ẹjọ́ àwọn ọmọ aláìníbaba* bó ṣe tọ́,Ẹjọ́ opó kì í sì í dé iwájú wọn.+
20 Àwọn tó ń sọ pé ohun tó dára burú àti pé ohun tó burú dára gbé,+Àwọn tó ń fi òkùnkùn dípò ìmọ́lẹ̀, tí wọ́n sì ń fi ìmọ́lẹ̀ dípò òkùnkùn,Àwọn tó ń fi ìkorò dípò adùn àti adùn dípò ìkorò!
12 Inú rẹ ni wọ́n ti gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ kí wọ́n lè ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀.+ Ò ń yáni lówó èlé,+ ò ń jẹ èrè* lórí owó tí o yáni, o sì ń fipá gba owó lọ́wọ́ ọmọnìkejì rẹ.+ Àní, o ti gbàgbé mi pátápátá,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.