Àìsáyà 11:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wọn ò ní fa ìpalára kankan,+Tàbí ìparun kankan ní gbogbo òkè mímọ́ mi,+Torí ó dájú pé ìmọ̀ Jèhófà máa bo ayé,Bí omi ṣe ń bo òkun.+ Sekaráyà 8:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Èmi yóò pa dà sí Síónì,+ èmi yóò sì máa gbé ní Jerúsálẹ́mù;+ wọ́n á máa pe Jerúsálẹ́mù ní ìlú òtítọ́,*+ wọ́n á sì máa pe òkè Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ní òkè mímọ́.’”+
9 Wọn ò ní fa ìpalára kankan,+Tàbí ìparun kankan ní gbogbo òkè mímọ́ mi,+Torí ó dájú pé ìmọ̀ Jèhófà máa bo ayé,Bí omi ṣe ń bo òkun.+
3 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Èmi yóò pa dà sí Síónì,+ èmi yóò sì máa gbé ní Jerúsálẹ́mù;+ wọ́n á máa pe Jerúsálẹ́mù ní ìlú òtítọ́,*+ wọ́n á sì máa pe òkè Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ní òkè mímọ́.’”+