Àìsáyà 19:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn odò á máa rùn;Àwọn ipa odò Náílì nílẹ̀ Íjíbítì máa fà, ó sì máa gbẹ táútáú. Àwọn esùsú* àti koríko etídò máa jẹrà.+
6 Àwọn odò á máa rùn;Àwọn ipa odò Náílì nílẹ̀ Íjíbítì máa fà, ó sì máa gbẹ táútáú. Àwọn esùsú* àti koríko etídò máa jẹrà.+