-
Émọ́sì 1:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ó sọ pé:
“Jèhófà yóò ké ramúramù láti Síónì,
Yóò sì gbé ohùn rẹ̀ sókè láti Jerúsálẹ́mù.
Ibi ìjẹko àwọn olùṣọ́ àgùntàn máa ṣọ̀fọ̀,
Ewéko orí òkè Kámẹ́lì á sì gbẹ dà nù.”+
-