Àìsáyà 55:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹ wá Jèhófà nígbà tí ẹ lè rí i.+ Ẹ pè é nígbà tó wà nítòsí.+ Émọ́sì 5:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Wá Jèhófà, kí o lè máa wà láàyè,+Kó má bàa bú jáde bí iná sórí ilé Jósẹ́fù,Kó má bàa jó Bẹ́tẹ́lì run láìsí ẹni tó máa pa iná náà.
6 Wá Jèhófà, kí o lè máa wà láàyè,+Kó má bàa bú jáde bí iná sórí ilé Jósẹ́fù,Kó má bàa jó Bẹ́tẹ́lì run láìsí ẹni tó máa pa iná náà.