Míkà 2:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Àwọn tó ń gbìmọ̀ ìkà gbé,Tí wọ́n ń gbèrò ibi lórí ibùsùn wọn! Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, wọ́n ṣe ohun tí wọ́n gbèrò,Torí pé agbára wọn ká a.+
2 “Àwọn tó ń gbìmọ̀ ìkà gbé,Tí wọ́n ń gbèrò ibi lórí ibùsùn wọn! Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, wọ́n ṣe ohun tí wọ́n gbèrò,Torí pé agbára wọn ká a.+