Ìdárò 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn ọ̀nà tó lọ sí Síónì ń ṣọ̀fọ̀, nítorí kò sí ẹni tó ń bọ̀ wá sí àjọyọ̀.+ Gbogbo ẹnubodè rẹ̀ di ahoro;+ àwọn àlùfáà rẹ̀ ń kẹ́dùn. Ẹ̀dùn ọkàn ti bá àwọn wúńdíá* rẹ̀, ó sì wà nínú ìbànújẹ́ ńlá. Ìdárò 2:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó ṣe àtíbàbà rẹ̀ ṣúkaṣùka+ bí ahéré tó wà nínú oko. Ó ti fòpin sí* àjọyọ̀ rẹ̀.+ Jèhófà ti mú kí a gbàgbé àjọyọ̀ àti sábáàtì ní Síónì,Kò sì ka ọba àti àlùfáà sí nígbà tí inú ń bí i gan-an.+
4 Àwọn ọ̀nà tó lọ sí Síónì ń ṣọ̀fọ̀, nítorí kò sí ẹni tó ń bọ̀ wá sí àjọyọ̀.+ Gbogbo ẹnubodè rẹ̀ di ahoro;+ àwọn àlùfáà rẹ̀ ń kẹ́dùn. Ẹ̀dùn ọkàn ti bá àwọn wúńdíá* rẹ̀, ó sì wà nínú ìbànújẹ́ ńlá.
6 Ó ṣe àtíbàbà rẹ̀ ṣúkaṣùka+ bí ahéré tó wà nínú oko. Ó ti fòpin sí* àjọyọ̀ rẹ̀.+ Jèhófà ti mú kí a gbàgbé àjọyọ̀ àti sábáàtì ní Síónì,Kò sì ka ọba àti àlùfáà sí nígbà tí inú ń bí i gan-an.+