-
Sekaráyà 5:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ pé, ‘Mo ti rán an jáde, yóò sì wọnú ilé olè àti ilé ẹni tó ń fi orúkọ mi búra èké; yóò wà nínú ilé náà, yóò sì jẹ ẹ́ run, pẹ̀lú àwọn ẹ̀là gẹdú àti òkúta rẹ̀.’”
-