-
1 Àwọn Ọba 1:33, 34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Ọba sọ fún wọn pé: “Ẹ mú àwọn ìránṣẹ́ olúwa yín dání, kí ẹ sì ní kí Sólómọ́nì ọmọ mi gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́* tèmi fúnra mi,+ kí ẹ wá mú un lọ sí Gíhónì.+ 34 Àlùfáà Sádókù àti wòlíì Nátánì yóò fòróró yàn án+ níbẹ̀ ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì; lẹ́yìn náà kí ẹ fun ìwo, kí ẹ sì sọ pé, ‘Kí ẹ̀mí Ọba Sólómọ́nì gùn o!’+
-