-
Jeremáyà 37:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Àmọ́ nígbà tó dé Ẹnubodè Bẹ́ńjámínì, ọ̀gá tó ń bójú tó àwọn ẹ̀ṣọ́, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Íríjà ọmọ Ṣelemáyà ọmọ Hananáyà mú wòlíì Jeremáyà, ó sì sọ pé: “Ọ̀dọ̀ àwọn ará Kálídíà lò ń sá lọ!”
-