Àìsáyà 40:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Kí ẹ mú kí gbogbo àfonífojì ga sókè,Kí ẹ sì mú kí gbogbo òkè ńlá àti òkè kéékèèké wálẹ̀. Kí ilẹ̀ tó rí gbágungbàgun di ilẹ̀ tó tẹ́jú,Kí ilẹ̀ kángunkàngun sì di pẹ̀tẹ́lẹ̀.+
4 Kí ẹ mú kí gbogbo àfonífojì ga sókè,Kí ẹ sì mú kí gbogbo òkè ńlá àti òkè kéékèèké wálẹ̀. Kí ilẹ̀ tó rí gbágungbàgun di ilẹ̀ tó tẹ́jú,Kí ilẹ̀ kángunkàngun sì di pẹ̀tẹ́lẹ̀.+