-
Máàkù 1:2-4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Bí a ṣe kọ ọ́ sínú ìwé wòlíì Àìsáyà pé: “(Wò ó! Màá rán ìránṣẹ́ mi ṣáájú rẹ,* ẹni tó máa ṣètò ọ̀nà rẹ.)+ 3 Ohùn ẹnì kan ń ké nínú aginjù pé: ‘Ẹ ṣètò ọ̀nà Jèhófà!* Ẹ mú àwọn ọ̀nà rẹ̀ tọ́.’”+ 4 Jòhánù Onírìbọmi wà nínú aginjù, ó ń wàásù pé kí àwọn èèyàn ṣèrìbọmi láti fi hàn pé wọ́n ti ronú pìwà dà, kí wọ́n lè rí ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ gbà.+
-
-
Jòhánù 1:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ọkùnrin kan wà tí a rán láti jẹ́ aṣojú Ọlọ́run; Jòhánù+ ni orúkọ rẹ̀.
-