Ẹ́kísódù 23:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “O ò gbọ́dọ̀ ni àjèjì lára. Ẹ mọ bó ṣe máa ń rí kéèyàn jẹ́ àjèjì,* torí àjèjì lẹ jẹ́ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Sekaráyà 7:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹ má lu opó tàbí ọmọ aláìníbaba* ní jìbìtì,+ ẹ má lu àjèjì tàbí aláìní ní jìbìtì,+ ẹ má sì gbèrò ibi sí ara yín nínú ọkàn yín.’+
9 “O ò gbọ́dọ̀ ni àjèjì lára. Ẹ mọ bó ṣe máa ń rí kéèyàn jẹ́ àjèjì,* torí àjèjì lẹ jẹ́ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+
10 Ẹ má lu opó tàbí ọmọ aláìníbaba* ní jìbìtì,+ ẹ má lu àjèjì tàbí aláìní ní jìbìtì,+ ẹ má sì gbèrò ibi sí ara yín nínú ọkàn yín.’+