-
Málákì 1:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Èmi Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ fún ẹ̀yin àlùfáà tó ń tàbùkù sí orúkọ mi+ pé: “‘Ọmọ máa ń bọlá fún bàbá,+ ìránṣẹ́ sì máa ń bọlá fún ọ̀gá rẹ̀. Torí náà, bí mo bá jẹ́ bàbá,+ ǹjẹ́ kò yẹ kí ẹ bọlá fún mi?+ Bí mo bá sì jẹ́ ọ̀gá,* ǹjẹ́ kò yẹ kí ẹ bẹ̀rù* mi?’
“‘Àmọ́, ẹ sọ pé: “Kí la ṣe tí a fi tàbùkù sí orúkọ rẹ?”’
-