Sáàmù 58:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Olódodo yóò máa yọ̀ nítorí pé ó ti rí ẹ̀san;+Ẹ̀jẹ̀ ẹni burúkú yóò rin ẹsẹ̀ rẹ̀ gbingbin.+ 11 Nígbà náà, aráyé á sọ pé: “Dájúdájú, èrè wà fún olódodo.+ Ní tòótọ́, Ọlọ́run kan wà tó ń ṣe ìdájọ́ ayé.”+
10 Olódodo yóò máa yọ̀ nítorí pé ó ti rí ẹ̀san;+Ẹ̀jẹ̀ ẹni burúkú yóò rin ẹsẹ̀ rẹ̀ gbingbin.+ 11 Nígbà náà, aráyé á sọ pé: “Dájúdájú, èrè wà fún olódodo.+ Ní tòótọ́, Ọlọ́run kan wà tó ń ṣe ìdájọ́ ayé.”+