Mátíù 9:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Jésù wá bẹ̀rẹ̀ sí í lọ káàkiri gbogbo ìlú àti abúlé, ó ń kọ́ni nínú àwọn sínágọ́gù wọn, ó ń wàásù ìhìn rere Ìjọba náà, ó sì ń wo onírúurú àìsàn àti onírúurú àìlera sàn.+ Máàkù 1:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Ó wá lọ ń wàásù nínú àwọn sínágọ́gù wọn káàkiri gbogbo Gálílì, ó sì ń lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde.+ Máàkù 6:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó yà á lẹ́nu pé wọn ò nígbàgbọ́. Ó sì lọ yí ká àwọn abúlé náà, ó ń kọ́ni.+
35 Jésù wá bẹ̀rẹ̀ sí í lọ káàkiri gbogbo ìlú àti abúlé, ó ń kọ́ni nínú àwọn sínágọ́gù wọn, ó ń wàásù ìhìn rere Ìjọba náà, ó sì ń wo onírúurú àìsàn àti onírúurú àìlera sàn.+