-
Lúùkù 6:22, 23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 “Aláyọ̀ ni yín nígbàkigbà tí àwọn èèyàn bá kórìíra yín+ àti nígbàkigbà tí wọ́n bá ta yín nù,+ tí wọ́n pẹ̀gàn yín, tí wọ́n sì fẹ̀sùn kàn yín* pé * ẹni burúkú ni yín nítorí Ọmọ èèyàn. 23 Ẹ yọ̀ ní ọjọ́ yẹn, kí ẹ sì fò sókè tayọ̀tayọ̀, torí, ẹ wò ó! èrè yín pọ̀ ní ọ̀run, torí àwọn ohun yẹn kan náà ni àwọn baba ńlá wọn máa ń ṣe sí àwọn wòlíì.+
-