Àìsáyà 40:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Koríko tútù máa ń gbẹ dà nù,Ìtànná máa ń rọ,Ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ Ọlọ́run wa máa wà títí láé.”+ Lúùkù 16:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ní tòótọ́, ó rọrùn kí ọ̀run àti ayé kọjá lọ ju kí ìlà kan lára lẹ́tà inú Òfin lọ láìṣẹ.+