Ẹ́kísódù 20:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “O ò gbọ́dọ̀ ṣe àgbèrè.+ Diutarónómì 5:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “‘O ò sì gbọ́dọ̀ ṣe àgbèrè.+ Lúùkù 18:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 O mọ àwọn àṣẹ náà pé: ‘O ò gbọ́dọ̀ ṣe àgbèrè,+ o ò gbọ́dọ̀ pààyàn,+ o ò gbọ́dọ̀ jalè,+ o ò gbọ́dọ̀ jẹ́rìí èké,+ bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ.’”+ Róòmù 13:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nítorí àkójọ òfin tó sọ pé, “O ò gbọ́dọ̀ ṣe àgbèrè,+ o ò gbọ́dọ̀ pààyàn,+ o ò gbọ́dọ̀ jalè,+ o ò gbọ́dọ̀ ṣojúkòkòrò”+ àti àṣẹ míì tó bá wà, ni a kó pọ̀ sínú ọ̀rọ̀ yìí, pé: “Kí o nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ.”+
20 O mọ àwọn àṣẹ náà pé: ‘O ò gbọ́dọ̀ ṣe àgbèrè,+ o ò gbọ́dọ̀ pààyàn,+ o ò gbọ́dọ̀ jalè,+ o ò gbọ́dọ̀ jẹ́rìí èké,+ bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ.’”+
9 Nítorí àkójọ òfin tó sọ pé, “O ò gbọ́dọ̀ ṣe àgbèrè,+ o ò gbọ́dọ̀ pààyàn,+ o ò gbọ́dọ̀ jalè,+ o ò gbọ́dọ̀ ṣojúkòkòrò”+ àti àṣẹ míì tó bá wà, ni a kó pọ̀ sínú ọ̀rọ̀ yìí, pé: “Kí o nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ.”+