Mátíù 18:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí náà, tí ọwọ́ rẹ tàbí ẹsẹ̀ rẹ bá ń mú ọ kọsẹ̀, gé e, kí o sì sọ ọ́ nù kúrò lọ́dọ̀ rẹ.+ Ó sàn fún ọ láti jogún ìyè ní aláàbọ̀ ara tàbí ní arọ ju kí a jù ọ́ sínú iná àìnípẹ̀kun+ pẹ̀lú ọwọ́ méjèèjì tàbí ẹsẹ̀ méjèèjì.
8 Torí náà, tí ọwọ́ rẹ tàbí ẹsẹ̀ rẹ bá ń mú ọ kọsẹ̀, gé e, kí o sì sọ ọ́ nù kúrò lọ́dọ̀ rẹ.+ Ó sàn fún ọ láti jogún ìyè ní aláàbọ̀ ara tàbí ní arọ ju kí a jù ọ́ sínú iná àìnípẹ̀kun+ pẹ̀lú ọwọ́ méjèèjì tàbí ẹsẹ̀ méjèèjì.