2 Bí wọ́n ṣe ń ṣiṣẹ́ Jèhófà,* tí wọ́n sì ń gbààwẹ̀, ẹ̀mí mímọ́ sọ pé: “Ẹ ya Bánábà àti Sọ́ọ̀lù+ sọ́tọ̀ fún mi kí wọ́n lè ṣe iṣẹ́ tí mo pè wọ́n sí.”+3 Lẹ́yìn tí wọ́n gbààwẹ̀, tí wọ́n sì gbàdúrà, wọ́n gbé ọwọ́ lé wọn, wọ́n sì rán wọn lọ.
23 Yàtọ̀ síyẹn, wọ́n yan àwọn alàgbà fún wọn nínú ìjọ kọ̀ọ̀kan,+ wọ́n gbàdúrà pẹ̀lú ààwẹ̀,+ wọ́n sì fà wọ́n lé Jèhófà* lọ́wọ́, ẹni tí wọ́n ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀.