3 Ẹ yin Ọlọ́run àti Baba Olúwa wa Jésù Kristi, torí nínú àánú rẹ̀ tó pọ̀, ó fún wa ní ìbí tuntun+ ká lè ní ìrètí tó wà láàyè+ nípasẹ̀ àjíǹde Jésù Kristi kúrò nínú ikú,+ 4 ká lè ní ogún tí kì í bà jẹ́, tí kò lábààwọ́n, tí kò sì lè ṣá.+ A tọ́jú rẹ̀ sí ọ̀run de ẹ̀yin+