-
Jóòbù 38:41Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
41 Ta ló ń pèsè oúnjẹ fún ẹyẹ ìwò,+
Tí àwọn ọmọ rẹ̀ bá ń ké jáde sí Ọlọ́run fún ìrànlọ́wọ́,
Tí wọ́n sì ń rìn kiri torí wọn ò rí nǹkan jẹ?
-