-
Lúùkù 6:41, 42Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
41 Kí ló wá dé tí ò ń wo pòròpórò tó wà nínú ojú arákùnrin rẹ, àmọ́ tí o ò kíyè sí igi ìrólé tó wà nínú ojú tìrẹ?+ 42 Báwo lo ṣe lè sọ fún arákùnrin rẹ pé, ‘Arákùnrin, jẹ́ kí n bá ọ yọ pòròpórò tó wà nínú ojú rẹ,’ nígbà tó jẹ́ pé ìwọ fúnra rẹ ò rí igi ìrólé tó wà nínú ojú tìrẹ? Alágàbàgebè! Kọ́kọ́ yọ igi ìrólé kúrò nínú ojú tìrẹ, ìgbà yẹn lo máa wá ríran kedere láti yọ pòròpórò tó wà nínú ojú arákùnrin rẹ.
-