Lúùkù 13:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 “Ẹ sa gbogbo ipá yín láti gba ẹnu ọ̀nà tóóró wọlé,+ torí mò ń sọ fún yín pé, ọ̀pọ̀ èèyàn máa fẹ́ wọlé àmọ́ wọn ò ní lè wọlé.
24 “Ẹ sa gbogbo ipá yín láti gba ẹnu ọ̀nà tóóró wọlé,+ torí mò ń sọ fún yín pé, ọ̀pọ̀ èèyàn máa fẹ́ wọlé àmọ́ wọn ò ní lè wọlé.