Lúùkù 6:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 “Ó mà ṣe fún yín o, nígbàkigbà tí gbogbo èèyàn bá ń sọ̀rọ̀ yín dáadáa,+ torí ohun tí àwọn baba ńlá wọn ṣe sí àwọn wòlíì èké nìyí.
26 “Ó mà ṣe fún yín o, nígbàkigbà tí gbogbo èèyàn bá ń sọ̀rọ̀ yín dáadáa,+ torí ohun tí àwọn baba ńlá wọn ṣe sí àwọn wòlíì èké nìyí.