-
Lúùkù 6:44Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
44 Torí èso igi kọ̀ọ̀kan la fi ń mọ̀ ọ́n.+ Bí àpẹẹrẹ, àwọn èèyàn kì í kó èso ọ̀pọ̀tọ́ jọ látorí igi ẹ̀gún, wọn kì í sì í gé èso àjàrà lára igi ẹlẹ́gùn-ún.
-