Mátíù 24:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “Nígbà náà, àwọn èèyàn máa fà yín lé ìpọ́njú lọ́wọ́,+ wọ́n á sì pa yín,+ gbogbo orílẹ̀-èdè sì máa kórìíra yín nítorí orúkọ mi.+
9 “Nígbà náà, àwọn èèyàn máa fà yín lé ìpọ́njú lọ́wọ́,+ wọ́n á sì pa yín,+ gbogbo orílẹ̀-èdè sì máa kórìíra yín nítorí orúkọ mi.+