-
Lúùkù 9:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Torí ẹnikẹ́ni tó bá tijú èmi àti àwọn ọ̀rọ̀ mi, Ọmọ èèyàn máa tijú ẹni yẹn nígbà tó bá dé nínú ògo rẹ̀ àti ti Baba àti ti àwọn áńgẹ́lì mímọ́.+
-