-
Lúùkù 12:51-53Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
51 Ṣé ẹ rò pé mo wá láti mú kí àlàáfíà wà ní ayé ni? Rárá o, mò ń sọ fún yín pé, dípò ìyẹn, ìpínyà ni.+ 52 Torí láti ìsinsìnyí lọ, ẹni márùn-ún máa pínyà nínú ilé kan, ẹni mẹ́ta sí méjì àti ẹni méjì sí mẹ́ta. 53 Wọ́n máa pínyà, bàbá sí ọmọkùnrin àti ọmọkùnrin sí bàbá, ìyá sí ọmọbìnrin àti ọmọbìnrin sí ìyá, ìyá ọkọ sí ìyàwó ọmọ rẹ̀ àti ìyàwó sí ìyá ọkọ rẹ̀.”+
-